Main Views
QA Views
About Transvision
Displaying 1 result:
Entity | en-US | yo |

Entity

all locales
android_l10n • mozilla-mobile • android-components • components • browser • errorpages • src • main • res • values • strings.xml mozac_browser_errorpages_net_interrupt_message |
en-US

The browser connected successfully, but the connection was interrupted while transferring information. Please try again.

The site could be temporarily unavailable or too busy. Try again in a few moments.

If you are unable to load any pages, check your device’s data or Wi-Fi connection.

yo

ìtàkùn ìgbáyé so mọ́ra dáadáa, ṣùgbọ́n àkùdé bá ìsomọ́ra náà nígbà tí à ń fi ìfitónilétí ránṣẹ́. Jọ̀wọ́ gbìyànjú sí i.

Ìkànnì náà lè má siṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀ tàbí kí ọwọ́ kún un. Gbìyànjú rẹ̀ sí i ní àìpẹ́.

Bí o kò bá lè jẹ́ kí ojú-ìwé rẹ siṣẹ́, yẹ ohun tí data rẹ fi ń siṣẹ́ wò tàbí ìsomọ́ Wi-Fi rẹ.

APIThese results are also available as an API request to search in
en-US or
yo.
Learn more about the Transvision API.
Please enable JavaScript. Some features won't be available without it.